YORÙBÁ LANGUAGE

Èdè Yorùbá

objective questions

Pick your answers from the alternatives given

Èdè Yorùbá

1 kí ni lẹ́tà àkọ́kọ́ nínú un álífábéétì Yorùbá

a b

b a

d c

2 Ònà mélòó ni a lè pín álífábéétì Yorùbá si

a ọ̀nà kan

b ọ̀nà méjì

d ọ̀nà igba

3 Álífábéétì mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá

a 5

b 15

d 25

4 Èwo ni fáwéèlì nínú un àwọn lẹ́tà wọ̀nyí

a h

b u

d n

5 Ò̀rọ̀ oní lèta méjì ni eyi

a bd

b bá

d gh

Àyọkà

Ka àyọkà yí kí o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tí ó tẹ̀lèe

KÍKÉ ÀTI ÀWỌN ỌMỌ O RÈ MÉ́FÀ

Ni àsìkò ìsinmi ni àwọn ọmọ mẹ́fà kan gbà láti ran òbí wọn lọ́wọ́.

Ní ọjọ́ ojà Akánrán ni wón ti ìlú Òjẹ́bòdé wá sí ọjà

Bólá ru àkàrà, Bùnmi ru ewébéè , Bósè ru àgbàdo, iyán ni Tóyìn ń tà , Níkèé ń tà isu , Eja tútù ni Túndùn ń tà . Ìyá wọn lyùn ni ó ń tójú owó

ÌBÉÈRÈ

1 kí ni orúkọ ìyá àwọn omo wònyí

a. Bóṣè

b. Túndùn

d. lyùn

2 Omo mélòó ni ó ń ran Ìyá yí lọ́wọ́

a. mẹ́wàá

b. mẹ́fà

d. mẹ́ta

3. Tani ó ń ta Isu

a. Níkèé

b. Bóṣè

d. Túndùn

4 Tani ó ń se Ìtọ́jú owó

a. Solá

b. Bólá

d. Ìyá a won

5. Kíni orúkọ míràn fún Iyùn

a. Kíké

b. Bólá

d. Solá

6 kíni àkọlé àyọkà yìí

a lyùn àti àwọn omo rè

b Kíké àti àwọn omo rè mẹ́fà

d. lyùn ati Kíké

7 kíni ẹ̀kọ́ tí o rí kó láti Inú àyọkà yìí

a. Mo gbọ́dọ̀ ran òbí mi Iówó

b. Ìwà búburú kò dára

d. a ati d

8 Ṣé o máa ń ran àwọn òbí re Iówó

a Bẹ́èni

b. Bẹ́ẹ̀ kọ́

d. a ati d

Àmì ohùn ọ̀rọ̀

9 fi àmì sí orí ọ̀rọ̀ yìí

Ewure (Goat)

a. Ewúré

b. Ewùre

d. Ewùré

10 fi ami si ori oro yii

Ile. (house)

a. Ilé

b. Ilẹ̀

d. Ile

Translation

Write the following names in Yoruba

1 light

a. Ìmò

b. Igi

d ìmólè

2. basket

a. àbọ̀

b. agbòn

d ìmólè

3. bag

a. Ìmò

b. Igi

d àpò

4. leave

a. ewé

b Isu

d dòdò

5. pot

a. Kókó

b. Igi

d Ìkòkò